Jẹnẹsisi 47:23 BM

23 Josẹfu sọ fún àwọn eniyan náà pé, “Àtẹ̀yin, àtilẹ̀ yín, láti òní lọ, mo ra gbogbo yín fún Farao. Irúgbìn nìyí, ẹ lọ gbìn ín sinu oko yín.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 47

Wo Jẹnẹsisi 47:23 ni o tọ