3 Farao bi àwọn arakunrin rẹ̀ léèrè irú iṣẹ́ tí wọ́n ń ṣe.Wọ́n dá Farao lóhùn pé, darandaran ni àwọn gẹ́gẹ́ bí àwọn baba wọn.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 47
Wo Jẹnẹsisi 47:3 ni o tọ