Jẹnẹsisi 47:30 BM

30 ṣugbọn gbé mi kúrò ní ilẹ̀ Ijipti kí o sì sin mí sí ibojì àwọn baba mi. Ibi tí wọ́n sin wọ́n sí ni mo fẹ́ kí o sin èmi náà sí.”Josẹfu dáhùn, ó ní, “Mo gbọ́, n óo ṣe bí o ti wí.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 47

Wo Jẹnẹsisi 47:30 ni o tọ