Jẹnẹsisi 48:17 BM

17 Nígbà tí Josẹfu rí i pé ọwọ́ ọ̀tún ni baba òun gbé lé Efuraimu lórí, kò dùn mọ́ ọn. Ó bá di ọwọ́ baba rẹ̀ mú láti gbé e kúrò lórí Efuraimu kí ó sì gbé e lórí Manase.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 48

Wo Jẹnẹsisi 48:17 ni o tọ