Jẹnẹsisi 48:2 BM

2 Nígbà tí wọ́n sọ fún Jakọbu pé Josẹfu ọmọ rẹ̀ dé, ó ṣe ara gírí, ó jókòó lórí ibùsùn rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 48

Wo Jẹnẹsisi 48:2 ni o tọ