Jẹnẹsisi 48:21 BM

21 Nígbà náà ni Israẹli sọ fún Josẹfu pé, “Àkókò ikú mi súnmọ́ etílé, ṣugbọn Ọlọrun yóo wà pẹlu rẹ, yóo sì mú ọ pada sí ilẹ̀ baba rẹ.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 48

Wo Jẹnẹsisi 48:21 ni o tọ