Jẹnẹsisi 48:4 BM

4 Ó ní, ‘N óo fún ọ ní ọpọlọpọ ọmọ, n óo sì sọ ọ́ di ọpọlọpọ ẹ̀yà, ati pé àwọn ọmọ ọmọ rẹ ni n óo fi ilẹ̀ náà fún, yóo sì jẹ́ tiwọn títí ayé.’

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 48

Wo Jẹnẹsisi 48:4 ni o tọ