Jẹnẹsisi 48:6 BM

6 Àwọn ọmọ tí o bá tún bí lẹ́yìn wọn, ìwọ ni o ni wọ́n, ninu ogún tí ó bá kan Manase ati Efuraimu ni wọn yóo ti pín.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 48

Wo Jẹnẹsisi 48:6 ni o tọ