Jẹnẹsisi 49:24 BM

24 sibẹsibẹ ọrùn rẹ̀ kò mì,apá rẹ̀ sì ń lágbára sí i.Agbára Ọlọrun Jakọbu ni ó fún apá rẹ̀ ní okun,(ní orúkọ Olùṣọ́-aguntan náà,tí í ṣe Àpáta ààbò Israẹli),

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:24 ni o tọ