Jẹnẹsisi 49:28 BM

28 Àwọn ẹ̀yà Israẹli mejeejila ni a ti dárúkọ yìí, ati ohun tí baba wọn wí nígbà tí ó súre fún wọn. Ó súre tí ó tọ́ sí olukuluku fún un.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:28 ni o tọ