Jẹnẹsisi 49:31 BM

31 Níbẹ̀ ni wọ́n sin Abrahamu ati Sara aya rẹ̀ sí, níbẹ̀ náà ni wọ́n sin Isaaki sí ati Rebeka aya rẹ̀, níbẹ̀ ni èmi náà sì sin Lea sí.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:31 ni o tọ