Jẹnẹsisi 49:6 BM

6 Orí mi má jẹ́ kí n bá wọn pa ìmọ̀ pọ̀,ẹlẹ́dàá mi má sì jẹ́ kí n bá wọn kẹ́gbẹ́.Nítorí wọn a máa fi ibinu paniyan,wọn a sì máa ṣá akọ mààlúù lọ́gbẹ́ bí ohun ìdárayá.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:6 ni o tọ