Jẹnẹsisi 49:9 BM

9 Juda dàbí kinniun,tí ó bá pa ohun tí ó ń dọdẹ tán,a sì tún yan pada sinu ihò rẹ̀.Tí ó bá nà kalẹ̀, tí ó sì lúgọ,kò sí ẹni tí ó jẹ́ tọ́ ọ.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:9 ni o tọ