Jẹnẹsisi 5:10 BM

10 Lẹ́yìn tí ó bí Kenani, ó gbé ẹgbẹrin ọdún ó lé mẹẹdogun (815) láyé, ó sì bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 5

Wo Jẹnẹsisi 5:10 ni o tọ