27 Gbogbo ọdún tí Metusela gbé láyé jẹ́ ẹẹdẹgbẹrun ọdún ó lé mọkandinlaadọrin (969) kí ó tó kú.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 5
Wo Jẹnẹsisi 5:27 ni o tọ