3 Nígbà tí Adamu di ẹni aadoje (130) ọdún, ó bí ọmọkunrin kan. Ọmọ náà jọ ọ́ gidigidi, bí Adamu ti rí gan-an ni ọmọ náà rí. Ó bá sọ ọ́ ní Seti.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 5
Wo Jẹnẹsisi 5:3 ni o tọ