Jẹnẹsisi 50:15 BM

15 Nígbà tí àwọn arakunrin Josẹfu rí i pé baba àwọn ti kú, wọ́n ní, “Ó ṣeéṣe kí Josẹfu kórìíra wa, kí ó sì gbẹ̀san gbogbo ibi tí a ti ṣe sí i.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 50

Wo Jẹnẹsisi 50:15 ni o tọ