Jẹnẹsisi 50:23 BM

23 Josẹfu rí ìran kẹta ninu àwọn ọmọ Efuraimu. Àwọn ọmọ tí Makiri ọmọ Manase bí, ọwọ́ Josẹfu ni ó bí wọn sí pẹlu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 50

Wo Jẹnẹsisi 50:23 ni o tọ