3 Ogoji ọjọ́ gbáko ni àwọn oníṣègùn máa fi ń tọ́jú irú òkú bẹ́ẹ̀. Àwọn ará Ijipti sì ṣọ̀fọ̀ rẹ̀ fún aadọrin ọjọ́.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 50
Wo Jẹnẹsisi 50:3 ni o tọ