8 ati gbogbo ìdílé Josẹfu àwọn arakunrin rẹ̀ ati ìdílé baba rẹ̀, àfi àwọn ọmọde, àwọn agbo ẹran, ati àwọn mààlúù nìkan ni ó kù sí ilẹ̀ Goṣeni.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 50
Wo Jẹnẹsisi 50:8 ni o tọ