Jẹnẹsisi 6:14 BM

14 Nítorí náà, fi igi goferi kan ọkọ̀ ojú omi fún ara rẹ. Ṣe ọpọlọpọ yàrá sinu rẹ̀, kí o sì fi ọ̀dà kùn ún ninu ati lóde.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 6

Wo Jẹnẹsisi 6:14 ni o tọ