18 Ṣugbọn n óo bá ọ dá majẹmu, o óo wọ inú ọkọ̀ náà, ìwọ pẹlu aya rẹ ati àwọn ọmọkunrin rẹ ati àwọn aya wọn.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 6
Wo Jẹnẹsisi 6:18 ni o tọ