3 OLUWA bá wí pé, “N kò ní jẹ́ kí eniyan wà láàyè títí lae, nítorí pé ẹlẹ́ran ara ni wọ́n. Ọgọfa (120) ọdún ni wọn yóo máa gbé láyé.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 6
Wo Jẹnẹsisi 6:3 ni o tọ