9 Ìtàn ìran Noa nìyí: Noa jẹ́ olódodo, òun nìkan ṣoṣo ni eniyan pípé ní àkókò tirẹ̀, ó sì wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu OLUWA.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 6
Wo Jẹnẹsisi 6:9 ni o tọ