Jẹnẹsisi 7:17 BM

17 Ìkún omi wà lórí ilẹ̀ fún ogoji ọjọ́. Omi náà pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ fi léfòó lójú omi.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 7

Wo Jẹnẹsisi 7:17 ni o tọ