Jẹnẹsisi 7:21 BM

21 Gbogbo àwọn ẹ̀dá alààyè tí wọ́n wà lórí ilẹ̀ ayé ni wọ́n kú patapata, ati ẹyẹ, ati ẹran ọ̀sìn, ati ẹranko, ati àwọn ohun tí wọn ń fàyà fà ati eniyan.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 7

Wo Jẹnẹsisi 7:21 ni o tọ