Jẹnẹsisi 7:7 BM

7 Noa wọ inú ọkọ̀ lọ, òun ati aya rẹ̀ ati àwọn ọmọ rẹ̀ pẹlu aya wọn, láti sá àsálà kúrò lọ́wọ́ ìkún omi.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 7

Wo Jẹnẹsisi 7:7 ni o tọ