11 Àdàbà náà fò pada ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ náà pẹlu ewé olifi tútù ní ẹnu rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni Noa ṣe mọ̀ pé omi ti fà lórí ilẹ̀.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 8
Wo Jẹnẹsisi 8:11 ni o tọ