Jẹnẹsisi 8:13 BM

13 Ní ọjọ́ kinni oṣù kinni ọdún tí Noa di ẹni ọdún mọkanlelẹgbẹta (601), omi gbẹ tán lórí ilẹ̀. Noa ṣí òrùlé ọkọ̀, ó yọjú wo ìta, ó sì rí i pé ilẹ̀ ti gbẹ.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 8

Wo Jẹnẹsisi 8:13 ni o tọ