Jẹnẹsisi 8:20 BM

20 Noa tẹ́ pẹpẹ kan fún OLUWA, ó mú ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu àwọn ẹran ati àwọn ẹyẹ tí wọ́n mọ́, ó fi wọ́n rúbọ lórí pẹpẹ náà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 8

Wo Jẹnẹsisi 8:20 ni o tọ