Kronika Kinni 10:1 BM

1 Ogun bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ará Filistia ati àwọn ọmọ Israẹli. Àwọn ọmọ Israẹli sá fún àwọn ará Filistia, wọ́n sì pa ọpọlọpọ àwọn ọmọ Israẹli ní orí òkè Giliboa.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 10

Wo Kronika Kinni 10:1 ni o tọ