Kronika Kinni 10:8 BM

8 Ní ọjọ́ keji, nígbà tí àwọn ará Filistia wá láti kó ìkógun, wọ́n rí òkú Saulu ati ti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹtẹẹta lórí Òkè Giliboa.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 10

Wo Kronika Kinni 10:8 ni o tọ