Kronika Kinni 11:24 BM

24 Àwọn ohun tí Bẹnaya, ọmọ Jehoiada, ṣe nìyí, tí ó sọ ọ́ di olókìkí, yàtọ̀ sí ti àwọn akọni mẹta tí a sọ nípa wọn.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 11

Wo Kronika Kinni 11:24 ni o tọ