Kronika Kinni 11:25 BM

25 Ó di olókìkí láàrin àwọn ọgbọ̀n ọ̀gágun; ṣugbọn òkìkí tirẹ̀ kò tó ti àwọn akọni mẹta náà. Dafidi bá fi ṣe olórí àwọn tí ń ṣọ́ ọba.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 11

Wo Kronika Kinni 11:25 ni o tọ