Kronika Kinni 11:4 BM

4 Dafidi ati àwọn ọmọ Israẹli lọ gbógun ti ìlú Jerusalẹmu, (Jebusi ni orúkọ Jerusalẹmu nígbà náà, ibẹ̀ ni àwọn ará Jebusi ń gbé.)

Ka pipe ipin Kronika Kinni 11

Wo Kronika Kinni 11:4 ni o tọ