Kronika Kinni 11:5 BM

5 Àwọn ará Jebusi sọ fún Dafidi pé, “O ò ní wọ ìlú yìí.” Ṣugbọn Dafidi ṣẹgun ibi ààbò Sioni, tí à ń pè ní ìlú Dafidi.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 11

Wo Kronika Kinni 11:5 ni o tọ