30 Láti inú ẹ̀yà Efuraimu, ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbẹrin (20,800) akikanju ati alágbára, tí wọ́n jẹ́ olókìkí ninu ìdílé wọn ni wọ́n wá.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 12
Wo Kronika Kinni 12:30 ni o tọ