Kronika Kinni 12:31 BM

31 Láti inú ìdajì ẹ̀yà Manase, ẹgbaasan-an (18,000) wá; yíyàn ni wọ́n yàn wọ́n láti lọ fi Dafidi jọba.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 12

Wo Kronika Kinni 12:31 ni o tọ