Kronika Kinni 13:14 BM

14 Àpótí Majẹmu Ọlọrun náà wà ní ilé Obedi Edomu yìí fún oṣù mẹta, OLUWA sì bukun ilé Obedi Edomu ati gbogbo ohun tí ó ní.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 13

Wo Kronika Kinni 13:14 ni o tọ