Kronika Kinni 14:1 BM

1 Hiramu, ọba Tire kó àwọn òṣìṣẹ́ ranṣẹ sí Dafidi, pẹlu igi kedari ati àwọn ọ̀mọ̀lé ati àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà láti bá a kọ́ ilé rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 14

Wo Kronika Kinni 14:1 ni o tọ