Kronika Kinni 15:16 BM

16 Dafidi pàṣẹ fún àwọn olórí ninu àwọn ọmọ Lefi pé kí wọ́n yan àwọn akọrin láàrin ara wọn, tí wọn yóo máa fi ohun èlò orin bíi hapu, dùùrù, ati aro dá orin ayọ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 15

Wo Kronika Kinni 15:16 ni o tọ