Kronika Kinni 15:17 BM

17 Nítorí náà àwọn ọmọ Lefi yan Hemani, ọmọ Joẹli ati Asafu, arakunrin rẹ̀, ọmọ Berekaya, ati àwọn arakunrin wọn láti ìdílé Merari, arakunrin wọn, Etani ọmọ Kuṣaaya.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 15

Wo Kronika Kinni 15:17 ni o tọ