Kronika Kinni 15:25 BM

25 Dafidi ati àwọn àgbààgbà Israẹli ati àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹrun ọmọ ogun bá lọ sí ilé Obedi Edomu, wọ́n lọ gbé Àpótí Majẹmu OLUWA pẹlu ayọ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 15

Wo Kronika Kinni 15:25 ni o tọ