Kronika Kinni 15:26 BM

26 Nítorí pé Ọlọrun ran àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n ru Àpótí Majẹmu OLUWA lọ́wọ́, wọ́n fi mààlúù meje ati àgbò meje rúbọ.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 15

Wo Kronika Kinni 15:26 ni o tọ