Kronika Kinni 15:27 BM

27 Dafidi ati gbogbo àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n ru Àpótí Majẹmu, ati àwọn akọrin ati Kenanaya, olórí àwọn akọrin wọ aṣọ funfun tí ń dán, Dafidi sì wọ efodu funfun.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 15

Wo Kronika Kinni 15:27 ni o tọ