Kronika Kinni 18:12 BM

12 Abiṣai, ọmọ Seruaya, ṣẹgun àwọn ará Edomu ní àfonífojì Iyọ̀, ó pa ẹgbaa mẹsan-an (18,000) ninu wọn.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 18

Wo Kronika Kinni 18:12 ni o tọ