Kronika Kinni 18:13 BM

13 Ó fi àwọn ọmọ ogun sí Edomu, gbogbo àwọn ará Edomu sì di iranṣẹ Dafidi. OLUWA fún Dafidi ní ìṣẹ́gun ní gbogbo ibi tí ó lọ.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 18

Wo Kronika Kinni 18:13 ni o tọ