Kronika Kinni 19:14 BM

14 Joabu ati àwọn ogun Israẹli súnmọ́ àwọn ọmọ ogun Siria láti bá wọn jà, ṣugbọn àwọn ọmọ ogun Siria sá fún wọn.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 19

Wo Kronika Kinni 19:14 ni o tọ