15 Nígbà tí àwọn ará Amoni rí i pé àwọn ará Siria sá, àwọn náà sá fun Abiṣai, wọn sì wọ ìlú wọn lọ. Joabu bá pada sí Jerusalẹmu.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 19
Wo Kronika Kinni 19:15 ni o tọ