Kronika Kinni 19:9 BM

9 Àwọn ogun Amoni tò lẹ́sẹẹsẹ siwaju ẹnubodè ìlú wọn, ṣugbọn àwọn ọba tí wọ́n bẹ̀ lọ́wẹ̀ wà lọ́tọ̀ ninu pápá.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 19

Wo Kronika Kinni 19:9 ni o tọ